abẹtẹlẹ

Yoruba

Etymology

From à- (nominalizing prefix) + bẹ̀ (to beg) + tẹ́lẹ̀ (before), literally prior begging.

Pronunciation

  • IPA(key): /à.bɛ̀.tɛ́.lɛ̀/

Noun

àbẹ̀tẹ́lẹ̀

  1. (idiomatic) bribe
    Synonyms: búráìbù, rìbá, owó-ẹ̀yìn, ọwọ́-kúdúrú, owó-àbẹ̀tẹ́lẹ̀
    Mi ò kí ń gbàbẹ̀tẹ́lẹ̀.I don't take bribes.
  2. (idiomatic, law) corruption
    Synonyms: ìwà-ìbàjẹ́, ìdíbàjẹ́
This article is issued from Wiktionary. The text is licensed under Creative Commons - Attribution - Sharealike. Additional terms may apply for the media files.