ibọn
Yoruba
Etymology 1
Possibly from ì- (“nominalizing prefix”) + bọn (“of a moderate entity springing off once suddenly”)
Pronunciation
- IPA(key): /ì.bɔ̃̄/
Noun
ìbọn
Derived terms
- arùgùdù ìbọn (“steel bullet”)
- ẹ̀tù ìbọn (“gunpowder”)
- igi ìbọn (“stock”)
- ọta ìbọn (“bullet”)
- ọ̀pá ìbọn (“barrel (of a gun)”)
- ta ní ìbọn (“to shoot”)
- àhàyá ìbọn (“pellet”)
- ìbọn arọ̀jò ọta (“machine gun”)
- ìbọn ayípo (“revolver”)
- ìbọn jagamù (“mortar”)
- ìbọn olójúméjì (“double-barrelled shotgun”)
- ìbọn ọwọ́ (“handgun”)
- ìbọn yíyìn
- ìbọn àgbá (“cannon”)
- ìbọn àgbéléjìká (“rifle”)
- ìbọn ìléwọ́ (“pistol, handgun”)
- ìdù ìbọn (“buttstock, butt”)
- ìrọ́bọnlù (“shelling”)
Pronunciation
- IPA(key): /ī.bɔ̃́/
Derived terms
- díbọ́n (“to feign”)
This article is issued from Wiktionary. The text is licensed under Creative Commons - Attribution - Sharealike. Additional terms may apply for the media files.