ajọ
Gun
Alternative forms
- ajɔ̀ (Benin)
Pronunciation
- IPA(key): /ā.d͡ʒɔ̀/
Derived terms
- ajọ̀wátọ́ (“merchant/trader”)
Yoruba
Pronunciation
- IPA(key): /ā.d͡ʒɔ̀/
Pronunciation
- IPA(key): /à.d͡ʒɔ̄/
Derived terms
- àjọ amójútó-ọ̀rọ̀-èbúté (“port authority”)
- àjọ amójútó-ìdánwò (“examination body”)
- àjọ aṣiṣẹ́pọ̀ (“consortium”)
- àjọ ẹgbẹ́ (“group of age-mates”)
- Àjọ Orílẹ̀-èdé Ajùmọ̀tepoolẹ̀-sórílẹ̀-èdèmìíràn (“OPEC”)
- àjọ ọ̀dọ́ (“council of youths”)
- àjọ àfòfindásílẹ̀ (“statutory authority”)
- àjọ àgbáyé (“international organization”)
- àjọ àwọn oníṣòwò (“chamber of commerce”)
- àjọ àwọn ọba (“council of traditional rulers”)
- àjọ-ìgbìmọ̀ (“council, assembly”)
- àjọbí (“relative, family member”)
- àjọdẹ (“hunting group”)
- àjọdì (“the act of being bound together”)
- àjọpinnu (“group decision”)
- àjọpínyà (“joint separation”)
- àjọrìn (“companionship”)
- àjọsọ (“group discussion”)
- àjọṣe (“to do something together, cooperation”)
- àjọṣepọ̀ (“collaboration”)
- àjọyọ̀ (“celebration”)
- àjọ̀dún (“anniversary”)
This article is issued from Wiktionary. The text is licensed under Creative Commons - Attribution - Sharealike. Additional terms may apply for the media files.