abo adiyẹ
Yoruba
Abo adìyẹ
kan pẹ̀lú ọmọ rẹ̀
Etymology
From
abo
(
“
female
”
)
+
adìyẹ
(
“
chicken
”
)
Pronunciation
IPA
(
key
)
:
/ā.bō ā.dì.jɛ̄/
Noun
abo adìyẹ
hen
Synonyms:
àgbébọ̀
,
obídìẹ
Abo adìyẹ
yẹn yín ẹyin púpọ̀ lọ́sẹ̀ tó kọjá yìí
―
The
hen
laid a lot of eggs this last week
Related terms
adìyẹ
(
“
chicken
”
)
adìẹ
(
“
chicken
”
)
àkùkọ
(
“
rooster
”
)
This article is issued from
Wiktionary
. The text is licensed under
Creative Commons - Attribution - Sharealike
. Additional terms may apply for the media files.