arun
Yoruba
Pronunciation
- IPA(key): /à.ɾũ̀/
Noun
àrùn
Derived terms
- aṣokùnfà-àrùn (“pathogen”)
- ẹ̀kọ́ àrùn-ara (“pathology”)
- ọ̀lẹ́dàrùn (“lazy person”)
- àjàkálẹ̀ àrùn (“epidemic, pandemic”)
- àrùn abẹ́gẹ̀ẹ́jà (“bacterial blight of cassava”)
- àrùn abàwọ̀jẹ́-sọnidiwèrè (“pellagra”)
- àrùn abò-ìgàyà (“pleurisy”)
- àrùn agbọ̀nà-ọ̀fun (“diphtheria”)
- àrùn amúṣurà (“yam tuber rot”)
- àrùn apèdèrẹ́ (“aphasia”)
- àrùn awọ-ara (“dematitis”)
- àrùn awú (“Cacao swollen shoot virus”)
- àrùn ẹ̀jẹ̀ (“hepatitis”)
- àrùn ẹ̀yi (“measles”)
- àrùn ibà (“malaria”)
- àrùn ilẹ̀-olóoru (“tropical disease”)
- àrùn jẹjẹrẹ (“cancer”)
- àrùn jẹnujẹsẹ̀ (“Foot-and-mouth disease”)
- àrùn jẹ̀dọ̀jẹ̀dọ̀ (“tuberculosis”)
- àrùn jàkùtẹ̀ (“elephantiasis”)
- àrùn kẹ́yùn-ún (“foot rot”)
- àrùn kányàn-án (“foot rot, infectious pododermatitis”)
- àrùn kòkòrò inú-afẹ́fẹ́ (“bacterial disease”)
- àrùn kòrìkòrì (“black pod disease”)
- àrùn máasùn-máasùn (“sleeping sickness”)
- àrùn okó-kíkú (“erectile dysfunction”)
- àrùn onígbáméjì (“cholera”)
- àrùn rẹwé-rẹwé (“stalk rot”)
- àrùn rọ́wọrọsẹ̀ (“polio, stroke”)
- àrùn sun-unrun-sun-unrun (“sleeping sickness”)
- àrùn sífílì (“syphillis”)
- àrùn yírùn-yírùn (“meningitis”)
- àrùn àbèǹtè (“disease”)
- àrùn àbímọ́ (“congenital”)
- àrùn àbínibí (“congenital disease”)
- àrùn àmọ́ (“pancreatitis”)
- àrùn àpò-ọkàn (“pericarditis”)
- àrùn ìbẹ̀rù-àjèjì (“xenophobia”)
- àrùn ìdílé (“genetic disorder”)
- àrùn-ẹ̀gbin-omi (“waterborne disease”)
- àrùn-ẹ̀jẹ̀-ríru (“hypertension”)
- àrùn-ẹ̀tẹ̀ (“leprosy”)
- àrùn-ipá (“tetanus”)
- àrùn-iwe (“Chronic kidney disease”)
- àrùn-oníkòkòrò-àìrí (“viral disease”)
- àrùn-ọkàn (“heart disease”)
- àrùn-ọpọlọ ada-èrò-òun-ìṣe-rú (“schizophrenia”)
- àrùn-ọpọlọ (“mental disease”)
- àrùn-àtọ̀gbẹ (“diabetes”)
- àrùn-àtọ̀sí (“gonorrhea”)
- àrùn-ètè (“lipomatosis”)
- àrùn-ìgbàgbé (“amnesia”)
- àrùn-ìtìsíwájú nípa ìkákò (“peristalsis”)
References
Etymology 2
50 | ||
← 4 | 5 | 6 → |
---|---|---|
Cardinal: àrún Counting: aárùn-ún Adjectival: márùn-ún Ordinal: karùn-ún Adverbial: ẹ̀ẹ̀marùn-ún Distributive: márùn-ún márùn-ún Collective: márààrùn-ún Fractional: ìdámárùn-ún |
Likely from Proto-Yoruboid *ɛ̀-lʊ́, cognate with Igala ẹ̀lú, Olukumi ẹ̀rú, Westerman proposes a reconstruction to Proto-Atlantic-Congo *-nu- (“five, hand”)
Pronunciation
- IPA(key): /à.ɾṹ/
Etymology 3
Cognate with Olukumi ẹrun and Igbo ọ́nú, proposed to be derived from Proto-Yoruboid *ɛ́-lʊ̃
Pronunciation
- IPA(key): /ā.ɾũ̄/
This article is issued from Wiktionary. The text is licensed under Creative Commons - Attribution - Sharealike. Additional terms may apply for the media files.