ọrọ-orukọ
Yoruba
Alternative forms
- OR (abbreviation)
- ọ̀rọ̀ orúkọ
Pronunciation
- IPA(key): /ɔ̀.ɾɔ̀.ō.ɾú.kɔ̄/
Hyponyms
- ọ̀rọ̀-orúkọ aláìṣeékà (“mass or uncountable noun”)
- ọ̀rọ̀-orúkọ aṣẹ̀pọ́n (“modifying noun”)
- ọ̀rọ̀-orúkọ aṣẹ̀yán (“modifying noun”)
- ọ̀rọ̀-orúkọ aṣorí (“head noun”)
- ọ̀rọ̀-orúkọ ayídà (“polymorphic noun”)
- ọ̀rọ̀-orúkọ nǹkan (“common noun”)
- ọ̀rọ̀-orúkọ àfòyemọ̀ (“abstract noun”)
- ọ̀rọ̀-orúkọ àgbájọ (“collective noun”)
- ọ̀rọ̀-orúkọ àkésí (“vocative noun”)
- ọ̀rọ̀-orúkọ àkójọ (“collective noun”)
- ọ̀rọ̀-orúkọ àrídìmú (“concrete noun”)
- ọ̀rọ̀-orúkọ-atọ́kasí (“referential noun”)
- ọ̀rọ̀-orúkọ-ibìkan (“proper noun for places”)
- ọ̀rọ̀-orúkọ-ènìyàn (“proper noun for humans”)
Derived terms
- ọ̀rọ̀-arọ́pò-orúkọ (“pronoun”)
Related terms
- ọ̀rọ̀-anítumọ̀-àdámọ́ (“lexis, content word”)
- ọ̀rọ̀-asopọ̀ (“conjunction”)
- ọ̀rọ̀-atọ́kùn (“preposition”)
- ọ̀rọ̀-ọgbọ́n (“phrase”)
- ọ̀rọ̀-àfetíyá (“ear-loan”)
- ọ̀rọ̀-àfojúyá (“eye-loan”)
- ọ̀rọ̀-àkànlò (“idiom”)
- ọ̀rọ̀-àpọ́nlé (“adverb”)
- ọ̀rọ̀-àpèjúwe (“adjective”)
- ọ̀rọ̀-àyálò (“loanword”)
- ọ̀rọ̀-èdè (“corpus, the words of a language”)
- ọ̀rọ̀-ìró-ìtumọ̀ (“ideophone”)
- ọ̀rọ̀-ìrótumọ̀ (“ideophone”)
- ọ̀rọ̀-ìṣe (“verb”)
References
- Awobuluyi, O. (1990) Yoruba Metalanguage (Ede-Iperi Yoruba) Vol. II (A Glossary of English-Yoruba Technical Terms in Language, Literature and Methodology), Ibadan: University Press Ltd.
- Awoyale, Yiwola (2008 December 19) Global Yoruba Lexical Database v. 1.0, volume LDC2008L03, Philadelphia: Linguistic Data Consortium, , →ISBN
- Nigerian Educational Research and Development Council (1992) Quadrilingual Glossary of Legislative Terms (English-Hausa-Igbo-Yoruba), Lagos: Federal Cabinet Office and Nigerian Educational Research and Development Council
This article is issued from Wiktionary. The text is licensed under Creative Commons - Attribution - Sharealike. Additional terms may apply for the media files.